A – Ajá
Dog
B- Bàtà
Shoe
D- Dígí
Mirror
E- Etí
Ear
Ẹ – Ẹja
Fish
F-Fìlà
Cap
Gb – Gbohùngbohùn
Loudspeaker
G- Gègé
Pen
H – Húkọ́
Cough
I – Ilé
House
J – Jagunjagun
Soldier
K – Kẹ̀kẹ́
Bicycle
L- Labalábá
Butterfly
M – Mààlúù
Cow
N – Ńlá
Big
O – Ojú
Eyes
Ọ – Ọmọ
Baby
P – Pẹ́pẹ́yẹ
Duck
R – Ràkunmí
Camel
S – Sálúbàtà
Slippers
Ṣ – Ṣòkòtò
Pants
T – Títì
Road
U – Únhùn
No
W – Wàrà
Milk
Y – Yẹtí
Earring