Kárọ́ọ̀tì
Carrot
Ọ̀gẹ̀dẹ̀
Banana
Ọsán
Orange
Ata
Pepper
Kùkúńbà
Cucumber
Ọsán wẹ́wẹ́
Lemon
Ọ̀pẹ̀-Òyìnbó
Pineapple
Ápù
Apple
Olú
Mushroom
Góbà / Gúáfà
Guava
Máńgòrò
Mango
Àgbọn
Coconut
Ìbẹ́pẹ
Papaya
Elégédé òyìnbó
Watermelon
Tòmátì
Tomato
Àwùsá Òyìnbó
Walnut
Ẹ̀pà Kajú
Cashew nut
Àlùbọ́sà
Onion
Aáyù
Garlic
Atalẹ̀
Ginger
Ẹ̀pà
Peanut
Ilá
Okra
Àlùbọ́sà Eléwé
Scallion
Ewébẹ̀
Leafy Greens
Elégédé
Pumpkin