Vernacular Hub – Yorùbá Sound Dictionary

Ẹbí – Family

Bàbá

Father

Ìyá

Mother

Òbí

Parent

Ọmọ Obìnrin

Daughter / Girl

Ọmọ Ọkùnrin

Son / Boy

Ọmọdé

Baby

É̩gbo̩n Obìnrin

Older Sister

É̩gbo̩n Ọkùnrin

Older Brother

Àbúrò Obìnrin

Younger Sister

Àbúrò Ọkùnrin

Younger brother

Ọnkú

Uncle

Àǹtí

Aunt

Ìyá Àgbà

Grandmother

Bàbá Àgbà

Grandfather

Ìyàwó

Bride

Ọkọ Ìyàwó

Groom

Àna

In-Law