Orí
Head
Ojú
Eyes
Irun
Hair
Etí
Ear
Ẹnu
Mouth
Èkẹ́
Cheek
Àgbọ̀n
Chin
Eyín
Teeth
Ètè
Lip
Imú
Nose
Iwájú Orí
Forehead
Èjìká
Shoulder
Ọrùn
Neck
Ahọ́n
Tongue
Ìka
Finger
Ọrùn Ọwọ́
Wrist
Ìgúnpá
Elbow
Apá
Arm
Ẹsẹ̀
Leg
Ojùgun
Shin
Gìgìrísẹ̀
Heel
Orúnkún
Knee
Ìka E̩sẹ̀
Toe
Ikùn
Stomach
Eyín
Back
Atẹ́lẹwọ́
Palm
Atẹ́lẹsè
Sole
Ìdodo
Navel
Ìpàkọ́
Back of head