Vernacular Hub – Yorùbá Sound Dictionary

Ònkà – Number

Òdo 

 Zero

Ọ̀kan

One

Èjì

Two

Ẹ̀ta

Three

Ẹ̀rin

Four

Àrún

Five

Ẹ̀fà

Six

Èje

Seven

Ẹ̀jọ

Eight

Ẹ̀sán

Nine

Ẹ̀wá

Ten

Ọ̀kànlá

Eleven

Èjìlá

Twelve

Ẹ̀talá

Thirteen

Ẹ̀rìnlá

Fourteen

Ẹ̀ẹ́dógún

Fifteen

Ẹ̀rìndínlógún

Sixteen

Ẹ̀tàdínlógún

Seventeen

Èjìdínlógún

Eighteen

Ọ̀kàndínlógún

Nineteen

Ogún

Twenty

Ọgbọ̀n

Thirty

Ogójì

Forty

Àádọ́ta

Fifty

Ọgọ́ta

Sixty

Àádọ́rin

Seventy

Ọ̀gọ́rin

Eighty

Àádọ́rin

December

Àádọ́run

Ninety

Ọgọrun

One Hundred