Vernacular Hub – Yorùbá Sound Dictionary

Oúnjẹ – Food

Ìrẹsì

 Rice

Ẹ̀wà

Beans

Ẹran

Meat

Ọbè

Soup

Àgbàdo

Corn

Búrẹ́dì

Bread

Wààra sóyà

Tofu

Dòdò

Fried Plantain

Àkàrà Òyìnbó

Cake

Midinmíìdìn

Candy

Ọ̀dùnkún

Potato

Iṣu

Yam

E̩ja

Fish

Bisikí / Kúkì

Cookie

Ẹyin

Egg

Òróró

Oil

Adìyẹ

Chicken

Ṣúgà

Sugar

Ṣokoléètì

Chocolate

Pankéèkì

Pancacke

Iyò̩

Salt

Pọfu Pọ́ọfù

Puff-Puff

Áísìkiriìmù

Ice cream

Oyin

Honey