Àga
Chair
Tábìlì
Table
Fìtílà
Lamp
Amóhuntutù
Refridgerator
Àtẹ́sílẹ̀
Carpet
Yàrá Ìgbàlejò
Living Room
Tẹlifíṣàn
Television
Yàrá Ìjẹun
Dinning Room
Yàrá Ìdáná Oúnjẹ
Kitchen
Ìkólẹ̀
Trash can
Ìkòkò
Pot
Àdìrò
Oven
Ìdérí
Lid / Cover
Abọ́ Pẹrẹsẹ
Plate
Ife
Cup
Àmúga-ìjẹun
Fork
Ṣíbí
Spoon
Ọ̀bẹ
Knife
Ilé Ìgbọ̀nsẹ̀
Toilet / Restroom
Balùwẹ̀
Bathroom
Dígí
Mirror
Búrọ̀ọ̀ṣì Ìfọyín
Toothbrush
Ọṣẹ Ìfọyín
Toothpaste
Aṣọ Ìnura
Towel
Ẹnu Ọ̀ṣọ̀ọ̀rọ̀
Faucet
Bàsíà Ìfọ̀wo
Sink
Òòyà
Comb
Oúnjẹ Àárọ̀
Breakfast
Oúnjẹ Ọ̀sán
Lunch
Oúnjẹ Alẹ́
Dinner
Yàrá
Bedroom
Ibùsùn
Bed
Ilẹ̀kùn
Door
Àjà
Attic
Ọ̀dẹ̀dẹ̀
Hallway
Òrùlé
Roof
Aláàbágbé
Neighbor
Ọgbà
Garden
Àlejò
Guest
Gègé
Pencil / Pen
Ìwe
Book
Ìfàlà
Ruler
Kọ̀ǹpútà
Computer
Ayélujára
Internet
Fóònù
Phone