Àgùnfọn
Giraffe
Erin
Elephant
Ejò
Snake
Ẹyẹ
Bird
Àkèré
Frog
Ẹkùn
Tiger
Erinmi
Hippopotamus
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Abilà
Zebra
Àgbánréré
Rhinoceros
Ẹlẹ́dẹ̀
Pig
Àgùntàn
Sheep
Mààlúù
Cow
Kìnnìún
Lion
Kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀
Fox
Ẹṣin
Horse
Eku
Rat
Ọ̀bọ
Monkey
Ehoro
Rabbit
Ológbò
Cat
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
Donkey
Ewúrẹ́
Goat
Ajá
Dog
Ọ̀wàwà
Cheetah
Ìjàpá
Tortoise
Ìgbín
Snail